OMA SE OO! Okunrin Kan Po Kun so Ni Ilu Ibadan

Ikunle abiamo, Okunrin kan po kun so ni Alalubosa GRA, Ibadan ni ipinle Oyo.

Ako mo okunrin naa tabi oruko re sugbon ari wipe, o pokun so ni ibi oko oju irin  ni Alalubosa.

IROYIN ti a gbo so wipe, se ni nooks owo Kan ri oku Okunrin yi Lori Ibi mangoro nigbatolufe lo se igbanse.

Nigerian Tribune sowipe, seni onisiwo yi fi gbe ta, ti o si kigbe pe ki won wa wo Ohun ti oju Ohun rii, eleyi ti o mu ki Awon eniyan ti owa nibe sare wa si Ibi ti il sele laabi yii ti sele ni Mile 110.

Won so wipe, wo ti lo fi Oro yii to Awon Olopa Iyaganku leti sugbon Awon Olopa eso fun won pe, Ibi ti Isele yii ti sele wa ni iyawo Awon Olopa Oko oju irin.

Nation ri gbo pe, won lo si ago Olopa to wa ni Dugbe lati lo so fun won Ohun ti won ri, sugbon Awon Olopa Ko lo si Ibi Ise yii.

Atun ri gbo wipe, nigbati ako IROYIN lati Nigerian Tribunelo si Ibi Isele yii, seni won si ba oku Okunrin Naa lori Ibi ti esinsin Bo sokoto rni too ripe, o ti to sii

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s