Foto: Fathia Balogun Gbe Ere Titun Miran Jade “Torera” Lakole Re

Aare AGN, Ibinabo Fiberesima fi Ewa ati Oge sise eu mi lopoplopo.
Se ni o wo asio alawo buluu ni ibi ayeye fifi lole ere titun kan ti Fathia Balogun sese gbe jade. Ni ibi ayeye naa ni ojo kejilelogun osu to koja yii ni. Ibigreatcoat bi ojo. Oya, or wo aworan Naa sii…..



oseere onitiata, FathiaKo ere titun re jade ‘Torera’ bi omo tuntun ni ose to koja, eleyi to waye ni gbongan 10 Degrees ni Oregun nilu Eko. Awon to Wasi ibe ni,  Ibinabo Fiberesima, Mercy Aigbe, Helen Paul, Bimbo Thomas, Kofi, Sikiratu Sindodo, Antar Laniyan Ati opolopo Awon it awo Oseere Onitiata

One thought on “Foto: Fathia Balogun Gbe Ere Titun Miran Jade “Torera” Lakole Re

Leave a reply to iroyinpye Cancel reply