Pa Kasumu Gbe Iyawo Fun Omo Re

omo bibi inu gbajugbaja oseere onitiata Yoruba, Kayode Odumosu ti a mo si Pa Kasumu, Olatunde Odumosu ni o ti gbe oloolufe re ni iyawo , Mojisola Adamolekun.olatunjiodumosu&wife
igbeyawo naa waye ni ojo Satide, March 1, 20the ni Blessed International School, Aboru, Iyana-Ipaja ni ilu Eko.
gegebi ase mo wipe, Pa Kasumu wa si ibi ayeye igbeyawo omo re to je omo odun metalogoji (37-year-old). Pa Kasumu se ojuse re bi baba Oko, o na won Lowo lopolopo, o si ba wo fi Ese RaJo.

Advertisements

One thought on “Pa Kasumu Gbe Iyawo Fun Omo Re

  1. Pingback: Pa Kasumu Gbe Iyawo Fun Akobi Okunrin Omo Re | iroyinpye

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s