Awon Osise Ati Onibara First Bank Ni Ilu Osogbo Sa Asala Fun Emi won Nigbati Won Ri Bombu Ninu Banki

imageLana ojo isegun Tuesday awon eleso abo ni First Bank Plc in Osogbo, ni ipinle Osun Ri ibu oloro ninu polythene bag ninu banki Naa..

Nise gbogbo Awon Osise Ile ise Naa ati Awon ONI Basra won free ge, ti won si se Bo lo yago lone ti won le gba jade.
Nise ni Awon ti won n ta Nkan legbe banki yii free ge ti won si fi Oja won sile, Awon Kan Ko tile pa ilekun Shobukola won de, ti won si Sa Asala fun Emi won. Talk fe ku!

Awon Olopa ti won ma n pe ni Anti- bomb police wa si Ibi Isele yii lati mu Bombu Naa Kuro.

Ijoba ipinle Osun State so wipe, Awon Ko le so Pato bi bombu Naa se wo ipinle Naa, sugbon won fura, eon si so wipe, Awon yio se iwadi bi Ise de inu bank naa
Ijoba ipinle Osun wa to Awon Olugbe ipinle Ohun ki won ma ba Oro Aje won lo, pe, won yio se iwadi ati wipe, won o ma dabobo Emi ati dukia won.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s