Ile Iwe Awon Irawo Oseere Ni Demolat School Of Performing Art

image.

Akoni ni won ninu pe ki a Ko Awon Osere ONI Tiata ni yiya ere. Lati atehin wa ni ati ri wipe, opolopo Awon oseere ni won so wipe Awon ni Ile iwe ti won ti Ko Eko nipa ere Sise. Awon akeko to kawe Kari ni Ile Iwe yii ni won gbayi lawujo. Won mo ere se won si mo Ohun ti o YE ki won se lasiko.
Demolat School of Performing Art je Ile Eko ti won ti n Ko eko nipa Cinematography, Make Up,Continuity,Lighting  ati bebe lo.Ile iwe yi ni a da sile ni Odun  2011.
Won ti gbe Awon ere jade Lori Telifisan ati wipe Awon ere olosoNaa Naa wa lara Awon ere ti won ti gbe jade bi,  Aworawo, Elemi Kukuru, Orisa Bi iya kosi ati wi pe niba yi, won ti Seyi ere Kan ti a pe ni a  Ireti Asan.  Awon ma n ko awon akeko won bi won se n ya ere, se ere ati bebe lo. Demolat School Of Performing Art Contact Numbers ni wonyi 08035612518  07083220667 BB: 2ADC103F  Email: demolatfilms@yahoo.co.uk

Ewo bi won se Ko ere sise

imageimageimageimageimageimageimageimageimage

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s