Yiya Ere “Ireti Asan” Movie Directed By Demolat

image

Yiya ere olosose ti a pe akole re ni “Ireti Asan” eleyi ti Demolat Dari re. Ni soki, ejeki aso nipa ere naa fun yin, omo okunrin kan ti oruko re n je Makanju ni awon obi re ran lo si ile iwe sugbon o darapo mo egbe okunkun nitori wipe, o wa lati idile ti won ko lowo pupo lowo. ni ojo kan, Asisie ba won, eleyi to je ki won pa gbogbo omo egbe okunkun naa pelu omo okunrin yii.  Olatubosun Otayemi (Demolat) lo dari yiya ere yii ati wipe awon osere to kopa no bi ere yii ni wonyi  Tunde Agboola, Samuel Opeyemi, Sulemon  Bukola , Kabir Afolayan,
, Feyisara Hassan , Akingbade  Rotimi , Ojo Olubunmi , Egunbiyi Olaide, Kehinde Ati Taiwo Tijani ati bebelo. Ilu Eko ni won ti ya ere yii. Ere yi koni pe dori Ero mohunmaworan yin. e o ma wo lose se.
Ewo Awon aworan yii, eleyi ti a ya, nigbati won n se akojoere ere yi.
imageimageimageimageimageimageimageimageimageimageimage

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s