Afihan Ere Titun When Dreams Fall Apart Yio Waye Loni

Ogbontarigi aya ere, ati ayaworan ere tiata ni ede geesi ati Igbo, Chico Ejiro ti gbe titun de o.  oni yii ni yio se afihan ere tuntun ti ape Akole re ni “When Dreams Fall Apart”. 
chico- when dream fall apart
E o ba Awon agba Oseere Onitiata pade ni bi ti a o ti se afihan ere ‘when dreams fall apart’ loni Ojo Isinmi,  Sunday, 9th March, 2014 ni 33 Social place off Ajose Adeogun, Victoria Island Lagos.  Red Carpet yio bere ni agog marun irole oni. 5pm. Awon Osere bi  Uche Jombo, Vincent Opurum, Emmanuel Mensah,ati bebe lo ni o kopa ninu ere yii. Eleyi ti Chico Ejiro Dari re.
ema salai ma wa o……


Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s