Ogbontarigi Oseere Onitiata, Ganiyu Oyeyemi (Ogunjimi) Fi Ipa Ba Omo Ore Re Lopo

ogunjimi arrested rape

Ganiyu Oyeyemi,  ti o je Ogbontarigi Oseere ni Owo Olopa ti te bayi ni ipinle Osun

Eni ti Awon enia mo si Ogunjimi ninu ere Tiata ni Obinrin Kan fi Esu if ipa bani lopo Kan

yoruba actor raped daughters friend

Omobinrin Naa so fun Awon Olopa wipe, se ni Ogunjimi fi ipa ba Ohun lopo ni Ile re ni Osogbo

Fun idabiloju pe otito ni omobinrin Naa n so, Dokita oloyinbo ti se ayewo fun omobinrin Naa, Osi ri daju pe otito ni

Gege bi Ase gbo, Iya omobinrin yi ati omobinrin yii ni o n gbe Lodo Ogunjimi, ti Osi n toji won,

If ipa bani lopo yii sele nigbati Iya omobinrin yii fi ilu Osogbo sile Glo si ilu Eko

Omobinrin yii so Isele Naa Aso fun Awon Ara Adugbo, won si ranlowo, won mu lo si ago Olopa ni Oke Baale

Bi Ase n soro yii, won Fâ Ejo Naa lo si SCID

Agbenuso fun Olopa ipinle Osun, Mrs Folashade Odoro so wipe, Ejo Naa ti wa ni ago Olopa bayi

Eniyan Kan lati agbo Awon Oseere so wipe, seni Ogunjimi so wipe, iro patapata ni

Advertisements

One thought on “Ogbontarigi Oseere Onitiata, Ganiyu Oyeyemi (Ogunjimi) Fi Ipa Ba Omo Ore Re Lopo

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s