Asiri Ajaale Ile Iku Ti Tu Ni Ilu Ibadan

https://i2.wp.com/www.tribune.com.ng/images/kidnap-den.jpg•Human skulls, rotten corpses litter scene
•Guns recovered; ATM, ID cards of victims found

Okiki Ajaale ile iku bi ti Boko Haram ni laye igba kan. Aimoye awon oniroyin olotelemuye ni won si ti sise iwadii lati mo ibi ti koto ti n gbe awon eniyan mi wa lati igba yii wa. Lara awon to ti topinpin iwadii ile iku naa ni Oloogbe Kola Olawuyi, eleyii ti enikeni ko le so pato ibi to wa gan-an.

Aimoye awon eniyan ni won jade nile ti won ko ni pada wale. Aimoye lo wo moto ero daran ki won to se agbako iku. Awon Yoruba si so wi pe omo eni ku, osan ju omo eni nu lo. Kini ka ti pe agbalagba to di ohun awati.

Mmmmmmh Nkan Mbe!

Olayemi Oniroyin, mo danu doru nibi lati taari alaye lekunrere senu Oluwatoyin Malik ati Saheed Salawu ti won se akojo iroyin naa fun ile ise iroyin Nigerian Tribune.

Oya oo

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s