Yee pa! Awon Olopa Fe Tu Were Ti Won Ka Eya Ara Eniyan Mo Lowo Sile?

image

Iroyin naa ko ti fidi mule, sugbon awon Yoruba ni eti oba nile eti oba loko eniyan ni i je bee.

Eniyan ti ko m’Eyo iru won ki mo Laipo. Won a ni Ibadan lo mo o mo Laipo, Laipo gangan n’Ibadan.
Ohun ti a gbo bayii ni wi pe awon kan ti n gbiyanju lati yo okunrin were ti won ka eya ara eniyan mo lowo ni ilu Ibadan kuro ni ago olopa. Won ni o seese ko je wi pe awon alagbara ti o n sise fun ni won wa nidi ati mu jade lago awon olopa ko to so gbogbo tikun re jade tan fun won.

Olayemi Oniroyin, ibeere mi ko po rara:
Ti won ba wa mu jade iru abo wo ni awon olopa fe je fun awon ara ilu ti won ran won nise?
Se won fe paro fun wa wi pe o ku sewon ni awon wa lo sin ni bonkele?
Abi won dogbon lati fi were gidi ropo jagunlabi onise ibi ti owo te labe afara ni?

Enikeni ko le so iru ogbon ti won fe fi mu okunrin naa jade lewon gan-an. Ati wi pe iroyin bee ko ti fidi mu gege bi mo se so saaju.

Sugbon, to ba lo je otito nko?

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s