Boko Haram Ti Lo Ka Goodluck Jonathan Mo Ile Ni Ilu Abuja

image
Awon omo Boko Haram bi mejidinlogun (18) ni won sun sinu eje nigba ti won se deede ota ibon awon osise alaabo ijoba apapo ti a mo si SSS. Awon omo Boko Haram bi ogun (20) ni owo won te, won si ti wa ni atimole bayii.

Awon omo alaabo Ijoba apapo bi meji naa fara pa ninu isele to wa ye naa.

Nibayii, baalu awon osise alaabo ti ijoba apapo ti gba oju orun kankan bayii ni ilu Abuja lati wa ibi to ku ti awon omo Boko Haram naa le fara pamo si ni awon agbegbe to sunmo ile ijoba apapo.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s