Oko Ofurufu Baalu Jabo Ni Ilu India

image
Ojo Eti to koja yii, 28-03-14, oko akeru ofurufu (cargo Plane) ilu India jabo loju orun eleyii ti awon awako baalu naa bi marun-un ti won wa ninu baalu naa padanu emi won nibi isele naa.

Madhya Pradesh ni ilu India la gbo wi pe baalu akeru naa jabo si. Afikun iroyin si fi ye wa wi pe baalu ti oruko re n je C-130J Hercules je orisii baalu kan eleyii ti won se ni ilu Amerika.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s