YORUBA MOVIE AWARDS: Eyi Ni Awon To Gba Ami Eye Ni YMAA 2014

image

Awon Oseere Onitiata Yoruba korajo si ilu Ibadan ni Civic Centre ni Agodi fun eto eleketa Iru re ti Ami eye fun Awon Ogbontarigi Onitiata Yoruba eyi ti a n pe Yoruba Movies Academy Awards (YMAA) ni Ana.

YMAA ni eto ami eye to yato ti Agbe kale, lati ma se, Kare, Ise lose Awon Oseere Ori itage Yoruba

Akoni Oseere bi Odunlade Adekola na Oseere bi  Muyiwa Ademola, Femi Adebayo ati Yomi Fash Lanso, ti o si gba a,the best Actor award nigbati Fathia Balogun gba the best Actress award lehin ti o jawe olubori nigbati o na Awon Oseere bii Funke Akindele, Iyabo Ojo and Ayo Adesanyo.

SPECIAL RECOGNITION
-Kola Ogunmola
-Akinwunmi Ishola
-Duro Ladipo
-Mama Awero
AWARDS
-Best Editor: Shola Ayorinde
-Best Cinematography: Richie Richie
-Best Marketer: Olasco
-Best Cultural Movie: Aramotu
-Best Cross Over Actor: Kelvin Ikeduba
-Best Support Actress: Joke Muyiwa
-Most Promising Actress: Memunat Yinusa
-Most Promising Actor: Tunde Owokoroniran
-Best Actor: Odunlade Adekola
-Best Actress: Fathia Balogun

 

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s