Foto: YEEPA!! Asiri Ibi Ti Awon Apaniyan Tun Ni Ilu Abeokuta

image

Asiri nla titu Bayii, Ile ti e n wo yii ni Ile ti Awon agbenu pa ma n gbe. Won ma n mu gbe gbogbo Awon eniyan ti won ba ti ji gbe wa si Ile yii ni ilu Abeokuta.

Isele yi sele loni nigbati okan lara Awon Alaboyun  merin ti won jigbe lati Ile Abia wa si ilu Abeokuta Sa mo Awon ajinigbe yii Lowo, ti Osi kigbe si Awon Ara Adugbo ki won Jowo gba Ohun Lowo Awon ajinipa yii.

Awon Ara Adugbo ba fi to Awon Olopa leti, lo ba do wahala.  Nigbati won de Ile won, Awon ajinigbe yii t salo, sugbon won ba Awon aboyun Meta ni Ile Naa ati Awon orisirisi eya Ara eniyan nibe. Ewo aworan Isele yii Bayii eleyi ti Isele ni ilu Abeokuta…image image image image image image image image image image image

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s