Oluso Aguntan Paito Ijo Maximum Deliverance Church Ni Olopa Ka Nibi Ti O ti N Ba Iyawo Soldier Lopo

image

Nigbati mo n dagba, mo ma n gbo pe, seni Awon ti won ba mu ti won ba n se pansaga ga agbere, seni AMA n mu won lo si odo Paito lati lo se itusile Kuro Lowo Emi kemi ti o n lo won. sugbon ni aye ti awa yii, seni Awon Paito gan ni a n mu ti won n se agbere won Loju paali

Oludasile Ijo Maximum Deliverance Church, Olusoaguntan John Simon ni Awon Olopa ka Nibiti o ti n se iseju se pelu iyawo Soldier (eri wipe, aye re ti baje) Seni Soldier yii yan Awon Olopa ki won ba Ohun so iyawo Ohun ati Paito yii.. sugbon a tun gbo wipe, Paito Simon le ma lo Awon Nkan bi Ogun fun Awon Obinrin ti o ba fe ba lopo ki won ma ba YE Ohun re.

bi e se ri ninu Foto yii, iyawo soldier ati Obinrin Kan ni won ka pelu Paito (twosome). Ewo Ohun bebe.lol

Paito aye re ti baje oooooo

image image image image

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s