Awon Agbenipa Ti Pa Omo Ile OAU ( Medicine Final Year Student)

imageViewers discretion

Elizabeth je Omo Ile iwe giga Obafemi Awolowo Univeristy Of Ile Ife, o si n ka bi Ase n je onise gun Oyinbo to damuse. O ti wa ni 500 level nigbati Isele buruku yii sele sii. Awon Omo egbe Okunkun ni won fe fi ipa ba lopo sugbon o yari patapata. Nitori idi eyi ni won fi fi ipa baa lopo,ti won si sha welewele. Agbo wipe, baba Elizabeth ti je Olorun Nipe nigbati owa ni Omo Odun bi mesan lati igba yii ni Iya re ti n da toji re titi ti Ofi de 500 level pelu Ise Alase.( caterer)

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s