Ikunle Abiyamo o! Okunrin Kan Gba Emi Ara Re Ni Akure Nitori Gbese To Je

image Okunrin asode Kan to je gbese lo ti so Ara re mo igi,a ri oku re Lara igi Kan leba odi papa isere ti ilu Akure ti won n Ko lo Lowo ni  morose Akure Silu Owo. O soju mi Koro Kan Isaac Okon so pe Oga oun pe oun  poun ri Okunrin Kan to n paara agbegbe Naa sugbon Nigba to de ibe lo ba oku Okunrin Naa,ewe,alukoro Ajo Olopa ipinle Ondo Wole Ogodo Nigba ti won n ba soro la tori Ero Ilewo,o ni won Ko tii fi Oro Naa to oun leti,amo, o ni oun a ran Awon Osise oun Sibe lati lo wadi Oro Naa.

imageimage

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s