Ile Adunlawo ti ni Awon Ero ayaworan to Dara julo, nitori pe seni a ma ri orisirisi Awon aworan bi eleyi Lori Ero Alatagba lojojumo.
Eleyi ti e n wo yii ni aya ni Ile Eko giga Univerisity of Kinshasa( UNIKIN) Nibiti, Olori asawari Nkan ti a n pe ni head of research and assistant professor ati minister of plan pelu Omo Ile iwe Kan ti won n se isekuse won ninu office re.
Eleyi je ibanuje ninu Iyanju eto Eko DR Congo. Photo won leleyii…
Advertisements