Ari Omo titun kan He Ninu Igbo Kan Ni Owerri, Isiala Ngwu Ni Ipinle Abia

imagePelu idunnu ati ibanuje ni fun Awon eniyan to wa ni agbegbe Owerrenta-Owerri ni Isialla Ngwu South Local government ni ipinle Abia nigbati won ri Omo Odun Kan he.

A gbo wipe, Awon omode n sere ninu Igbo, ti won si n wa Eyin ope (Palm Kermel) nigbati won ri Omo titun yi ninu Igbo. Won Ko mo Bo ya, seni won ji Omo Naa gbe tabi, seni Iya re gbe sonu.

bi Oti le je pe a Ko ti mo idi eleyi yi Omo titun Naa fi do gbagbe sinu Igbo, sugbon Awon Olugbe ilu yii so wipe, iwa buruku gbaja ni iwa ti Iya Omo Naa wu.

Awon ti won ri Omo Naa he, ti gbe Omo na fun Awon Olopa ti o wa ni Owerrenta fun itoju ati wipe, boya Iya Omo Naa le pada wa gbe Omo yi.

 

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s