Femi Solar Yio Se Ifilole Orin Re Titun ” Oreofe” Ni Ilu Ibadan

 

Femi Solar
Femi Solar

A o da ariya Bole ni ilu ibadan ni Ojo Ojobo 22 nd May 2014, nigbati, Femi Oorun yio se ifilole Orin re titun ti a pe Akole re ni ” oreofe”.

Pyemedia jabo pe, ayeye yi ni City People Entertainment, Yemi Sonde Entertainment, FIBAN ti ipinle Oyo, Gaad Communications se agbateru.

Awon olorin Ojo Naa ni wonyi, King Sunny Ade, Pasuma Oganla 1, Lanre Teriba( Atorise), Adonai, Adewale Ayuba, 9ice, Dele Taiwo, Oritsefemi, Ibabie, Adegbodu Twins, Dele Bravo, Tunde F Tundey, Lizzy Babalola and Kabri Ere Asalatu at bebe lo. “

Eleyi je ara oto lati owo Femi Oorun, eniti gbogbo eniyan mo si Femi Solar.
Sorosoro ni, Wale Dada ni o ma dari eto naa, ti yio waye ni Genesis Suites & Hall Beside Fire Brigade, Challenge Ibadan ni Ojobo, Thursday 22nd May, 2014
Fun alaye lekun rere, epe ero ibani soro yii: 08055455154, 08023331618, 08097770221, 08033502839

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s