Foto: Lanre Teriba fi Orin Emi Gbe Olorun Ga ni Ilu Oba

image image

Bi ese mo pe, Ogbontarigi olorin Emi ni, Lanre Teriba ti bere irin Ajo lo si ilu Oba lati Nkan bi Osu Marun Odun yii.

O bere irinke rindo re ni inu Ijo Grace Prayer Ministries ni Maryland USA fun ayeye AJODUN Ijo Naa fun Ojo meta gbako, eyi ti Crown entertainment se agbateru re. O tun Korin ni ilu New York eleyi ti Iyalaje promotions se agbateru ati Awon Ibi ayeye miran lo.

Ni bayi, o ti gbaradi lati lo si Texas ni Osu to n Bo yii, September 5th,  eyi ti First Omega and Sammclef Entertainment se onigbowo. Phil- Dem entertainment ni o ma gba Lanre  lalejo  ni Chcago ni ojo kejila osu ton bo, September 12th. o si tun ma Korin ni Awon ibi ayeye miran ni Osu October.

“Mo dupe Lowo Olorun. Awon Ololufe mi ni ilu Oba nibi yi feran Awon Ara otun ti mo mu wo Orin mi, won si feran Orin mi titun “He Reigns”. O je Ibukun fun mi” – Lanre Teriba so be, ni gba ti a fi Oro wa lenu wo.

Titi di Igbayi, Larin gbogbo Awon olorin eemi ti o ma n wa si ilu Oba,  Atorise ti je eni Akoko ti yio ni Ero ati Awon ti won wa lati gbo Orin re ni Ibi ayeye ni ilu Okere.

Ki ama se gbagbe pe, won si ti fi Lanre Teriba je Igbakeji Ààrẹ Ni Performing Musician Association of Nigetia (PMAN).  Eleyi wu ni Lori pupo.

Ti e ba fe pe Atorise si Ibi ayeye yin, e lo si Ori Ero Alatagba http://www.lanreteriba.com tabi e fi iwe ranse si Info@lanreteriba.com

Ni Bayii e je ki awo aworan lati Grace Prayer Ministry nibi ti Atorise ti Korin……..

image image image image

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s