Ogbontarigi Onitiata Yoruba, Tunde Dickson Se Igbeyawo Alarinrin (Foto)

image image

Gbajugbaja Oseere onitiata ati agbe Tiata ere Yoruba jade, Tunde Dickson ti amo wipe o je okan ninu Awon Apon Larin Awon elere Tiata Yoruba ti se Igbeyawo pelu Ololufe re  Adeola Alao ni  Ikoyi Registry, Lana Ojo Satide,  13th September 2014.

Adeola je Omo bibi ilu- Oyo ni ipinle Oyo nigbati Tunde Dickson je Omo bibi Ilu Ondo ni ipinle Ondo.
Awon Ogbontarigi Onitiata ere Yoruba ni won wa si Ibi ayeye Naa, Awon bi, Soji Omobanke, Solade Blessing Okeye, Yemi Solade, Olumide Adedayo, Moses Adeyemo, Itele Ralph Niyi Steven, Korede Magic Michael, Ajani Eda, Michael Skelewu, Prince Segun, Segun Baraka ati bebe lo.
Tunde Dickson n ya Awon ere Kan Lowo Bayii, ti won yio gbe wa si Cinema fun wiwo Laide.. Efara bale ki Ewo Awon Foto lati Ibi Igbeyawo………..

imageimageimageimageimageimageimageimageimage

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s