Soja to fipa ba omo Poli Ibarapa sun ti rewon he

image Lori eôsun ti woôn fi kan sôoôja kan to n sôisôeô ni baraaki ilu Sôaki, nipinleô O·yoô, pe o fipa ba oômoôoôleewe gbogbonisôe (Ibarapa Polytechnic) Eruwa lasôepoô, ileesôeô ologun ileô yii ti gbe igbimoô kan dide lati toôpinpin isôeôleô oôhun lati le moô iru ijiya to toô si oôkunrin jagunjagun naa, iyeôn bi aje iwa ibajeô oôhun ba sôi moô oôn lori. Sôoôja oôhun ti woôn pe orukoô eô ni Benedict Ignatius to jeô oôkan ninu awoôn ikoô ajoô alaabo ijoôba ipinleô O·yoô ti a n pe ni Operation Burst ni woôn lo fipa ba Omidan Dupeô, akeôkoôoô ileewe gbogbonisôe Ibarapa Polytechnic, Eruwa, ta a fi ojulowo oruko bo lasôiiri lasôepoô loôjoô Eôti, Fraide, oôjoô koôkandinloôgboôn, osôu keôjoô, oôdun yii. Geôgeô bi asegbo sôe gboô, Dupeô gbalejo oôreô eô kan, bo si sôe n pada loô sile leôyin to sin in dieô ni nnkan bii aago meôwaa aaboô aleô lo pade sôoja Operation Burst yii ti iyeôn si fi eôsun buruku kan an. Oni oômoô eôgbeô okunkun ni, ati pe o ni lati boô ara eô sihooho niwaju oun ki oun le wo o boya o ni ami tawoôn eeyan naa maa n sôe sibi koôloôfin ara woôn. Dupeô ko moô pe oôroô yii koôja bi oun sôe ro o, afi nigba ti oôkunrin jagunjagun naa fipa tan an loô sinu igbo to si fa oôbeô yoô si i ko too fipa ba a lasôepoô laimoôye igba laarin bii wakati meôta. Leôyin wakati marun-un ti Dupeô ti boô sinu igbekun yii la gboô pe ori ko o yoô to fi ri oôna sa loô moô oôkunrin naa loôwoô ni nnkan bii aago meôta aaboô oru. Bi ileô aaroô oôjoô keji sôe moô, iyeôn loôjoô Abameôta (Satide), oôgboônjoô, osôu keôjoô, oôdun yii lo loôoô fi isôeôleô oôhun to awoôn agbofinro leti ni tesôan woôn to wa niluu Eruwa peôlu iranloôwoô oôkunrin kan to ti figba kan ri jeô olori eôgbeô awoôn akeôkoôoô nileewe gbogbonisôe ilu Eruwa. DPOtesôan Eruwa, DSP Kayode Adigun, funra eô la gboô pe o sôaaju awoôn agbofinro ti woôn mu oômoôbinrin to n keôkoôoô imoô iroyin yii loô sileewosan fun ayeôwo, eyi to fidi eô muleô pe eônikeôni ko ba obinrin akeôkoôoô naa lasôepoô. Sôugboôn ohun ti a tun gboô ni pe nisôe lawoôn alakooso ileewosan oôhun, iyeôn ileewosan ijoôba ipinleô O·yoô to wa niluu Eruwa doôgboôn si oôroô ayeôwo naa. Woôn ni nisôe ni woôn doôgboôn tan Dupeô jade peôlu bi woôn sôe soô pe ko loôoô ra iboôwoô ti woôn yoo fi sôe ayeôwo fun un wa, nigba ti yoo fi de, dokita atawoôn kan to lagbara nibeô ti sôeto awuruju abajade ayeôwo to maa jade. Awoôn ti woôn lanfaani lati ba Ignatius soôroô ko too di pe woôn ko sôeôkeôsôeôkeô boô oô loôwoô ti woôn si gbe e ju satimoôle soô fawoôn akoôroyin pe Ignatius funra eô ti gba pe loootoô loun jeôbi eôsun ifipa-bani-lopoô ti woôn fi kan an, o si beôbeô fun idariji eôsôeô. Sôugboôn nigba to ya lo pa ohun da, to si soô pe oun kan yeô ara oômoô naa wo lasan lati wo o boya o ni ami oômoô eôgbeô okunkun lara ni, bo tileô jeô pe oun da igbaju bo o nigba to koô lati teôle asôeô oun. Nigba to n royin ohun ti oju eô ri loôwoô oôkunrin sôoôja naa fawoôn oniroyin loôseô to koôja, Dupeô sôalaye peôlu omije loju pe, “Loôjoô koôkandinloôgboôn, osôu keôjoô, oôdun yii, mo sin oôreô mi to wa mi wa sile loô. Ba a sôe tuka ti mo n pada loô sinu yara mi ni mo pade sôoôja yeôn loju oôna to si soô pe oômoô eôgbeô okunkun ni mi. “Mo ni emi ki i sôe oômoô eôgbeô okunkun, beôeô lo ni oun maa gbe mi loô, pe ki n jokoo sori oôkada oun. Mo ni ko fi mi sileô ki n maa loô, bo sôe fa oôbeô yoô niyeôn pe oun maa gun mi pa ti mo ba koô lati foôwoô sowoô poô peôlu oun. Mo jokoo sori oôkada, o gbe mi loô si oôfiisi awoôn Operation Burst to wa ni Eruwa, nigba ta a debeô lo fipa woô mi loô si koôroô kan nibeô, o ni ki n boô asôoô mi sileô ki oun wo o boya mo ni tatuu lara. Mo ni ko joôoô ko fi mi sileô, pe mi o ni nnkan to joô oô, sôugboôn o ni oun maa dunbu mi bii eôran ti mi o ba gba foun. Oni aimoôye eeyan loun ti pa danu, beôeô loun ti gbe woôn sin leôseôkeôseô, ati pe toun ba pa emi naa, ko si eôni to maa moô pe oun loôwoô ninu iku mi.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s