O ku ojo die ki Dolapo ati afesona re segbeyawo loko pa a n’Ibadan

image

 

Loôseô to koôja yii, isôeôleô kan to gba omije loju awoôn eeyan sôeôleô n’Ibadan, peôlu bi obinrin alaboyun kan to ti da oôjoô igbeyawo soôna, Doôlapoô Salawu, sôe pade iku ojiji. Arabinrin alaboyun osôu meôrin naa, eôni to ti da oôjoô igbeyawo soôna pe osôu keôwaa yii ni oun yoo di eôru oun loô sile oôkoô oun pade iku ojiji, nigba ti ijanu oôkoô agbepo kan sôadeede ja, to si loôoô sôeku pa a nibi to duro si peôlu afeôsoôna reô ni eôgbeô ileepo Adisa to wa lojuna maroseô Ibadan si O·yoô nigba ti woôn n ti ori oke adura ti woôn ti loôoô gbadura lori igbeyawo woôn boô. A gboô pe deôreôba oôkoô epo beôntiroolu miiran, eyi ti moôto woôn fori soô naa padanu eômi reô loju-eôseô. Iwadii fi han pe nisôe ni oôkoô afeôsoôna Doôlapoô sare fo kuro nibi to duro si, eyi ni ori si fi ko o yoô nibi isôeôleô oôhun. Nnkan to fa isôeôleô yii ni bi oôkoô Nissan Micra kan sôe sôadeede ya bara lati gbero lai wo gilaasi fun oôkoô to n boô leôyin reô. Nisôe ni oôkoô epo Iveco ti noômba reô jeô KAT 149 XA ti a gboô pe o gbepo lita eôgbeôrun loôna meôtaleloôgboôn (33, 0000) to wa leôyin eô sare yiwoô seôgbeôeô ko ma baa koôlu oôkoô naa, sôugboôn to loôoô roôlu oôkoô Mack ti noômba reô jeô AGL 23 XA to gbepo lita eôgbeôrun loôna marundinlaaadoôta (45,000), ko too waa koôlu obinrin oloogbe naa. Akoôroyin wa gboô pe loju-eôseô lawoôn osôisôeô alaabo eôsôoô oju popo ti debi isôeôleô oôhun, ti woôn si ko ipa to joôju. Gbogbo akitiyan akoôroyin wa ni akoko ti a n koôroyin yii lati fidi isôeôleô naa muleô loôdoô awoôn alasôeô to yeô lo ja si pabo, nitori gbogbo bi a sôe n pe noômba woôn ni ko lo

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s