Egbe The Golden Movie Ambassador Se Ibewo Si PM News

image image Loni yii ti nse Ojo kokanlelogun ni Awon Omo egbe The Golden Movie Ambassador se ibe wo si PM News lati lo bere fun ifowosowopo won fun itesiwaju egbe Naa. Ninu Oro re, Ààrẹ egbe yii Gboriyin fun PM News fun kiko IROYIN to ni itumo ati fun Ise takuntakun won lati le je iwe IROYIN Akoko ti yio ma gbe IROYIN jade ni Irole ojojumo. Saidi Balogun fi Emi Imore Han si Awon Akoroyin ni PM News bi won se ma n gbe IROYIN otito jade, APAPA nipa Awon Osseere Onitiata. Ninu Oro tire, Folukeumosen Daramole to je okan ninu Awon Asiwaju egbe Naa fi ehunu Han bi Awon enia se ma n ri Awon Oseere Onitiata bi Ise ere lasan. O wipe, Awon je Ogbontarigi ninu Ise ti Awon yan laayo, ti Osi jepeimage image image image image image image image image image image image image image

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s