Asise nla: CNN pa Obama lai ku re (Foto)

image

 

 

“Ko seni ti Ko koja aside laye” CNN ti a n wo pe, won Ko le sasise nipa gbagbe IROYIN jade Naa ma ti se aside nla, eleyi to je wipe, to ba je Ile adulawo wa Africa, seni, Olori orile ede Naa a pa lase pe ki won da eni ti o aside Naa duro.

Ni Ana ode yii ni a gbo wipe, CNN focused News ti won n soro Lori Omo Ogun ‘Seal’ ti o Lohun ti pa Osama bin laden ni Odun 2011 ni Abbottabad, seni won ba si oruko Osama Ko, ti won ba Ko ‘Obama’. “SEAL WHO CLAIMS HE KILLED OBAMA UNDER ATTACK”

Gege bi a se gbo, se ni aside oruko Naa wa Lori Ero Amohunmaworan fun bi Iseju Kan gbako.

lehin ti won ri wipe, aside oruko wa, ni won ba tete paare, ti won Ko, ‘Osama’

 

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s