E Kaabo sinu Osu Ope (December) Justpye

image

 

Ninu Osu Ope yii ni ati n se opolopo asaro Lori Ohun ti a gbe se ninu Odun 2014. Laisi ani ani, mo Lero wipe, Ohun ti e pinnu lati se lati January Odun yii ni e ti gbese. Nitori Naa, ti e Ko ba le se gbogbo re, EFi  le Olorun lowo, lati fun yin ni anfani lati pari re losu yii.

mo fe fi Asika yii dupe Lowo gbogbo Awon to n se akitiyan  pe ki ede Yoruba ma ba parun ni Asika wa yii….Inu mi dun pupo pe, gbogbo Ohun ti mo pinnu re lati se ni mo n se.

e seun pupo…..E Jowo, e tun Bo ma polongo ikan ni yii. E ku Ewu Odun. Osu yii atu wa Lara o. Amin

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s