Adigun Jale Se Ikolu si Ile Ifowopamo UBA ni Ilu Ado Ekiti

image

Awon Adigun jale ti kolu Ile ifowopamo Kan UBA,  ni ilu Ado Ekiti Lana

Ikolu yii mu Emi eniyan Kan lo, lehin igba ti won gbe opolopo Owo lo lati ATM banki Naa.

Gegebi IROYIN ti agbo, oku enia Kan wa ninu Oko Awon Olopa, ti won si gbe lo lehin ti Awon Alase Ile ifowopamo yii fi ope si ago Awon Olopa to wa ni agbegbe won.

Alukoro fun Awon Olopa, Taiwo Lakanu so fun Awon Akoroyin wipe, Awon ole Naa de Ile ifowopamo UBA ni Nkan bi ago Meji Osan ni Ojoru. O so wipe, okan ninu Awon Ole Naa ni Owo Awon ti Te, ti Osi ti n ka boro boro fun wa, eleyi yio u ki Owo Te Awon. Egbe re to Ku.

Awon onibaara Ile ifowopamo UBA ti won ba Awon Akoroyin soro, fi aidunnu won Han pe, Ikolu orisirisi ni Awon Adigun jale n se si ipinle Ekiti, won si wa pe Akiyesi Gomina ipinle Naa, Ayo Fayose, ki o wa woroko fi sada.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s