Olopa Sharia Mu Awon Okunrin ti won ba arawonlopo Lojo Igbeyawo Ako si Ako ni ilu Kano

image

Okunrin Kan ti o ma n ba Awon Okunrin elegbe re lopo, Faruk Maiduguri ni Owo Awon Olopa Sharia ba ni Abaa ni ilu Kano nigbati o n se Igbeyawo pelu Ololufe re (Okunrin) ni ilu Kano.

Olopa Sharia ni won mu Arakunrin yi pelu Awon Alejo re bi Merinla ni Ibi ayeye naa

Olopa Sharia ni won so wipe, won gbo wipe, Awon Okunrin n se Igbeyawo fun Ara won ni ilu Kano, ni papa julo, Faruk ati Abba ni won n se Igbeyawo Lowo, nigbati Awon ya Bo ibe ti won si mu won.

Agbo wipe, Faruk fi Ikede jade Lori Whatsapp wipe ki Awon ore ati ojulumo wa ba won yo fun ayeye Igbeyawo won.

Sugbon Awon Okunrin yii so wipe, iro ti o jina si otito ni, wipe, se ni Awon n se ayeye Ojo Ibi.

Awon mejeji n koju ewon Odun merinla Bayii.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s