Owo Olopa Te Femi Adebayo Lehin Isele Awon Adigun Jale

image

LAarin Awon Ogbontarigi Oseere ONitita Yoruba, FEmi ADebayo je Akinkanju Oseere ti o ma se ere Tiata yato si Awon elegbe re.

Femi Adebayo tun je agba oje pe ki aya ere fin igbadun awon ololufe re. Gege bi e ti mo Jelili, oruko ti Awon Ololufe re ma n pe, o ti wa gbe ere titun miran jade….Ninu ere yii ni Femi ti se ogboju Olosa, Ole ati agbebon. Ohun ati Awon egbe Adigun jale re. Ninu ere yii ni Owo Olopa Te won, ti won si fi imu won jo fin. Won ya ere yii ni ilu Oyo ni ipinle Oyo. Awon Oseere ti o wa ninu ere Naa Adebayo Salami, Faithia Balogun,Kelvin Ikeduba, Dele Odule, Sanyeri, Aina Gold, Aisha Lawal, Itele,Austin Emmanuel, Ibrahim Chatta, Seyi Ashekun, Bigval ati bebe lo.

Tope Adebayo lo Dari ere Naa. Ewo Awon aworan lati Ibi ti ati ya ere yii…

image image image image image

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s