Obesere da ile ise Ounje ati Ayeye sise sle ni ilu London,Lagos,Ibadan,Abuja ati Abeokuta

obeseresatt

Ogbontarigi Olorin onifuji Abass Akande

Obesere ti da ile ise nla igbaafe igbalode.Olu ile ise igbafe re ni

ilu Eko.Obesere naa ni o ni Adunni Foods ti o wa ni Canning Town, East London.

Lori wipe kini idi re ti o fi da ile ise naa sile,Obesere dahun:

“Emi kin se opee ninu ise yii,sugbon mo wa fi asiko yii fi oju mi han pe, emi ni oludasile ile ise naa nitori wipe mo ti n ni irogba re lati da ile ise naa sile. Mo nife ki n ma se ounje, nitori idi eyi ni mo fi da catering service sile. Olu ile ies na wa ni Plot 73a, Babatunde Onigbanko Way, Amuwo Odofin Lagos.

Eka re wa ni Mokolani ilu Ibadan, Lantoro Abeokuta ati

Maitama, Abuja.

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s