Oriire dee, Fayose fi owo si N237million Fun Awon Osise ijoba to ba fe ya Owo Ra Motor

Ayo Fayose, Ekiti state governor.

Gomina ti ipinle Ekiti, Ayodele Fayose, ti fi owo si iwe fun owo itanran N236,860,000 fun rira oko fun awom osiise bi 773 ni ipinle naa

Komisanna fun eto isuna, Toyin Ojo, so eleyi ni ilu Ado-Ekiti, pe Yiya owo naa, bi nkan bi N80,000 si N1.5 million, ni won yio san fun awon ti won yege lati le yaa.

O so wipe, grade levels awon osiise bi 773 ni won yio je anfani naa.

Komisana naa tun so wipe, awon ti ko ba ni anfani lati gba owo naa, ki won se suuru, nitori wipe, Ijoba yio fun won ni kete ti awon ti won ba koko fun ba da owo naa pada.

O gba awon ti oruko won ba jade ki won lo wo ni ofiisi, Accountant general

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s