Iku doro: Oseere onitiata, Olakunle Akindele dagbere fun Aye

 

Ni eka ti tiata Yoruba, Sikiru Adeshina ti amo si (Arakangudu) je ipe Olorun lehin arun Okan ati Mike Odiachi ti eka ede Geesi, ti oku lehin arun ito Sugar (diabetes and high blood pressure) ati eje riru, ni won ti pada nu onitiata miran.
Ati ti kuro lori ofo ti  Shakirudeen Olakunle Akindele, ni Olakunle ba je Olorun nipe.Sahara Weekly Magazine reports that,   so wipe, Okunrin yii, ti o je omo odun merinlelogbon, ku ni ojoru 17th of feb 2016 ti a si ti sin, ni ilana ti musilumi ni ojo keji.
Wonni Kunle Akindele ni o ti n gbiyanju lati se awon ere jade ati wipe, o ti n ko pa ninu yiyia ere ati didari ere ori itage, ni iku ba mulo.
Ofi awon obi saye, Iyawo ati omo re okunrin ni ilu oba UK.

IMG-20160222-WA0054
Olakunle sese gba kaardi irinan lo si ilu oba UK ti oti n wa fun odun merin , Lati lo darapo mo aya re ni isele buburu yi sele. Ki Olorun te si afefe rere
Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s