Olumide Bakare ti kuro ni UCH, Ibadan leyin ti o gba itoju to peye tan

sic
Oseere onitiata, Olumide Bakare ti kuro ni ile iwosan UCH Ibadan nibiti o ti n gba itoju.
Se bi e mo wipe,Olumide Bakare fi lede pe ohun nilo Iranlowo owo bi 7million naira fun itoju.
Nibayi, eleyi je iroyin ayo ni eka ere ti Nollywood Yoruba.

Olumide Bakare ni awon Dokita so wipe,o ni aisan inu eje ni odun 2013 , eleyi ti o di aisan nla ti won n pe ni “Dissecting Aortic Aneurysm and Pulmonary Embolism”

Aisan eleyii ti o ma ba isan ara enia je, ti o ma h ba eje naa je.

Abere kan je #14,000 ni ile iwosan,ti a n pe ni Clexane

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s