Oseere onitiata, Tonia Ferrari Okoro Daku ni ibi isinku Iya re

toni
Arewa Tonia Ferrari Okoro fi eru si awon to wa si bi oku Iya re lara ni ilu Eko.
SAHARA WEEKLY NG Reports that,A gbo wipe, se ni Iya re to je omo orile ede Cameroun dubule aisan fun bi Osu Merin, Tonia si se itoju re gidi gan ni..titi to fi je eleda nipe.

Tonia ti o je oseere ori itage lo si Ile iwosan ti iya re ti n gba itoju, lehin ti o ri awon Dokita tan, o lo si ile, lati lo setoo,ounje fun Iya re.

Aburo re ba pe, Tonia pe, ki o ma se iyonu mo, nitori wipe, Iya won ti je ipe Olorun. Bi Tonia se gba ipe yii, ni o daku lo, lehin ti won ji pada saye.

The biggest of all was the one she did at Atan Cemetery when her mum’s remains was about to be interred.
Eyi ti a tun wa gbo ni wipe, se ni oseere onitiata yii ba inu je gidigan ni, ni ibi ti won ti n sin Iya re, ti o si tun daku looo.
A nki Ferrari pe, o ku asehinde mama
Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s