UTME ti se wa yamayama, egba wa o:Iwode awon akeko loni ni ipinle Eko

UTME protest6

Won ni UTME ti se wa yamayama, se ni, awon akeko to n ko idanwo UTME loni se iwode ita gbangba lo si ile igbimo asofin ni ipinle eko lati fi enuhu won  han pe, awon ko nife bi UTME se n se awon. e wo aworan naa….. Continue reading “UTME ti se wa yamayama, egba wa o:Iwode awon akeko loni ni ipinle Eko”

Advertisements

Foto: Iyawo Taiwo ati Kehinde Adegbodu wa si ori eto Bebe nlo Lori Africa Magic Yoruba 157/5

Instagram media adegbodu_kenny - Twins wit Seun Adeagbo "BEBE NLO" on africa magic

Eto kan lori AfricaMagic Yoruba ikanni 157 lori DStv ati ikanni  kaarun lori GOtv ti a n pe ni “Bebe nlo” eyi ti Samuel Adeagbo n se olootu ati atokun re ma gba awon gbajugbaja olorin kan lalejo….
Eto Bebe nlo lori Africa magic Yoruba je eto ti a ti n gborin yi fun awom Toko taya, awon ibeji, awon ebi fun igba gbepo ninu ife.
Nitori naa, e ku o ju lona akanse eto yi ti Samuel Adeagbon tu ko re, ti yio si fi awon iyawo awon olorin ni Taiwo ati Kehinde Adegbodu han…

Continue reading “Foto: Iyawo Taiwo ati Kehinde Adegbodu wa si ori eto Bebe nlo Lori Africa Magic Yoruba 157/5”

Femi Solar ati Mega 99 Abel Dosumu gbe orin jade

 Pelu Awo Orin titun ti o n bo lona, Femi Solar ti n gbaradi lati se awon naa sita, fun awon ololufe re.
Omoba Abel Dosumu ti inagi re je Mega 99  ti darapo mo Femi lati ko orin jade, eleyi ti yio wa ninu awo orin titun naa. Awon iko, Justpye se alaba pade awon gbajugbaja olorin yii ni Ilu Ibadan.

Aso fun yin tele pe, Femi ma se ifilole awo orin titun jade All White Album launch ati sise studio re ni ilu ibadan..

Iku doro: Oseere onitiata, Olakunle Akindele dagbere fun Aye

 

Ni eka ti tiata Yoruba, Sikiru Adeshina ti amo si (Arakangudu) je ipe Olorun lehin arun Okan ati Mike Odiachi ti eka ede Geesi, ti oku lehin arun ito Sugar (diabetes and high blood pressure) ati eje riru, ni won ti pada nu onitiata miran.
Ati ti kuro lori ofo ti  Shakirudeen Olakunle Akindele, ni Olakunle ba je Olorun nipe.Sahara Weekly Magazine reports that,   so wipe, Okunrin yii, ti o je omo odun merinlelogbon, ku ni ojoru 17th of feb 2016 ti a si ti sin, ni ilana ti musilumi ni ojo keji.
Wonni Kunle Akindele ni o ti n gbiyanju lati se awon ere jade ati wipe, o ti n ko pa ninu yiyia ere ati didari ere ori itage, ni iku ba mulo.
Ofi awon obi saye, Iyawo ati omo re okunrin ni ilu oba UK.

Continue reading “Iku doro: Oseere onitiata, Olakunle Akindele dagbere fun Aye”

Omokunrin kan fi ibon pa omo odun merinla obinrin nitori wipe,ko gba lati ni ajosepo pelu re

Omo Obinrin Indian. (File copy)

 

Ni Uttar Pradesh  orile ede India, owo awon Olopa ti te awon Omode kunrin meji kan ti won yinbon pa omobinrin omo odun merinla.
A gbo wipe, seni won fe fi ipa ba won lo po, ti won ko je ki won ri imu mi.
Okan ninu awon omokunrin naa ba gbe ibon fun omo binrin yii ti e n wo aworan re loke yii, lo ba je Olorun nipe.