Nje o mo pe Baba Latin rin irin ajo lo si ilu Okere?

Instagram media mr_latin_d_comedian - iam me. #no competition # no tension

Bolaji Amusan ti gbogbo enia mo si Mr Latin ti pada de lati ilu okere… Continue reading “Nje o mo pe Baba Latin rin irin ajo lo si ilu Okere?”

Advertisements

Bimbo Akintola ati Francis Duru be awon ti Boko haram so di alaini ile lori mo ni ilu Maiduguri

3454356_123282031876750945884769567931547n
Oseere onitita, Bimbo Akintola ati Francis Duru, ni ojo isinmi ti o koja lo be awon eni yan ti won fara gba isele, boko haram ni ibi ti won fi won pamo si, ti ijoba ti n toju won, ni Maiduguri.

Continue reading “Bimbo Akintola ati Francis Duru be awon ti Boko haram so di alaini ile lori mo ni ilu Maiduguri”

Egba wa lowo awon Fulani Daran daran Mujeje(Blood sucking Fulani Herdsmen -Ara ileto Agatu ke Jade

agatu1

Loni ni orilu orile ede Naijiria, awon enia Agatu se ilede ifehunu han si ijoba, ni pa lilo si National Assembly ni Abuja… Awon Fulani daran daran se iku pa awon agbe ilu naa….. Continue reading “Egba wa lowo awon Fulani Daran daran Mujeje(Blood sucking Fulani Herdsmen -Ara ileto Agatu ke Jade”

Advertisements

Femi Solar ati Mega 99 Abel Dosumu gbe orin jade

 Pelu Awo Orin titun ti o n bo lona, Femi Solar ti n gbaradi lati se awon naa sita, fun awon ololufe re.
Omoba Abel Dosumu ti inagi re je Mega 99  ti darapo mo Femi lati ko orin jade, eleyi ti yio wa ninu awo orin titun naa. Awon iko, Justpye se alaba pade awon gbajugbaja olorin yii ni Ilu Ibadan.

Aso fun yin tele pe, Femi ma se ifilole awo orin titun jade All White Album launch ati sise studio re ni ilu ibadan..

Advertisements

Iku doro: Oseere onitiata, Olakunle Akindele dagbere fun Aye

 

Ni eka ti tiata Yoruba, Sikiru Adeshina ti amo si (Arakangudu) je ipe Olorun lehin arun Okan ati Mike Odiachi ti eka ede Geesi, ti oku lehin arun ito Sugar (diabetes and high blood pressure) ati eje riru, ni won ti pada nu onitiata miran.
Ati ti kuro lori ofo ti  Shakirudeen Olakunle Akindele, ni Olakunle ba je Olorun nipe.Sahara Weekly Magazine reports that,   so wipe, Okunrin yii, ti o je omo odun merinlelogbon, ku ni ojoru 17th of feb 2016 ti a si ti sin, ni ilana ti musilumi ni ojo keji.
Wonni Kunle Akindele ni o ti n gbiyanju lati se awon ere jade ati wipe, o ti n ko pa ninu yiyia ere ati didari ere ori itage, ni iku ba mulo.
Ofi awon obi saye, Iyawo ati omo re okunrin ni ilu oba UK.

Continue reading “Iku doro: Oseere onitiata, Olakunle Akindele dagbere fun Aye”

Advertisements

Omokunrin kan fi ibon pa omo odun merinla obinrin nitori wipe,ko gba lati ni ajosepo pelu re

Omo Obinrin Indian. (File copy)

 

Ni Uttar Pradesh  orile ede India, owo awon Olopa ti te awon Omode kunrin meji kan ti won yinbon pa omobinrin omo odun merinla.
A gbo wipe, seni won fe fi ipa ba won lo po, ti won ko je ki won ri imu mi.
Okan ninu awon omokunrin naa ba gbe ibon fun omo binrin yii ti e n wo aworan re loke yii, lo ba je Olorun nipe.

 

Advertisements

Oseere onitiata, Tonia Ferrari Okoro Daku ni ibi isinku Iya re

toni
Arewa Tonia Ferrari Okoro fi eru si awon to wa si bi oku Iya re lara ni ilu Eko.
SAHARA WEEKLY NG Reports that,A gbo wipe, se ni Iya re to je omo orile ede Cameroun dubule aisan fun bi Osu Merin, Tonia si se itoju re gidi gan ni..titi to fi je eleda nipe.

Tonia ti o je oseere ori itage lo si Ile iwosan ti iya re ti n gba itoju, lehin ti o ri awon Dokita tan, o lo si ile, lati lo setoo,ounje fun Iya re. Continue reading “Oseere onitiata, Tonia Ferrari Okoro Daku ni ibi isinku Iya re”

Advertisements

Olumide Bakare ti kuro ni UCH, Ibadan leyin ti o gba itoju to peye tan

sic
Oseere onitiata, Olumide Bakare ti kuro ni ile iwosan UCH Ibadan nibiti o ti n gba itoju.
Se bi e mo wipe,Olumide Bakare fi lede pe ohun nilo Iranlowo owo bi 7million naira fun itoju.
Nibayi, eleyi je iroyin ayo ni eka ere ti Nollywood Yoruba.

Continue reading “Olumide Bakare ti kuro ni UCH, Ibadan leyin ti o gba itoju to peye tan”

Advertisements

Pasiitoo! Social Media Daru,nigbati Pastor fi aworan bi ose fi Owo ko Osan meji Iyawo re lowo

american-pastor-and-his9ja-wife-4

Pasito… Ewo ohun ti Pastor yii se si Iyawo re! Social Media Daru,nigbati Pastor fi aworan bi ose fi Owo ko Osan meji Iyawo re lowo. (U.S Pastor Breaks The Internet In Controversial Photos Where He Grabbed His Nigerian Wife’s B00bs) Oya, e wo nkan ti Pastor yii see… Continue reading “Pasiitoo! Social Media Daru,nigbati Pastor fi aworan bi ose fi Owo ko Osan meji Iyawo re lowo”

Advertisements

Oriire dee, Fayose fi owo si N237million Fun Awon Osise ijoba to ba fe ya Owo Ra Motor

Ayo Fayose, Ekiti state governor.

Gomina ti ipinle Ekiti, Ayodele Fayose, ti fi owo si iwe fun owo itanran N236,860,000 fun rira oko fun awom osiise bi 773 ni ipinle naa

Komisanna fun eto isuna, Toyin Ojo, so eleyi ni ilu Ado-Ekiti, pe Yiya owo naa, bi nkan bi N80,000 si N1.5 million, ni won yio san fun awon ti won yege lati le yaa.

Continue reading “Oriire dee, Fayose fi owo si N237million Fun Awon Osise ijoba to ba fe ya Owo Ra Motor”

Advertisements